-
Ọ̀rẹ́ =Friend
-
Ojúsàájú = Bias, unfair, favouritism, partiality
-
Ilẹ̀ / Ìsàlẹ̀ = Down, downstairs, floor, ground
-
Ọ̀ta = Enemy
-
Ways to use "Àbá = Suggestion" in sentences in Yoruba
-
Abayéjẹ́ / Ọ̀bàyéjẹ́ =
-
Àyípadà / Ìyípadà
-
Abà = village, hurt, hamlet
-
Ìmoore = Gratitude, thankfulness, appreciation...
-
Dá gbé = To Live alone
-
Owó Orí = Tax
-
Ìfidunni = Deprivation
-
Orin = Song
-
Ajìjàgbara:Ajàfúnẹ̀tọ́ = An activist
-
Gbé = Live, Living, Lived
-
Dá ṣe é : dá nìkan ṣe é = to do it alone
-
Dá lọ : dá nìkan lọ = to go alone
-
Explaining the difference between Jẹ and Jẹun in Yoruba when we talk about food
-
Dá rìn = to walk alone
-
Ìsimi = Rest : relaxation : holiday : vacation
-
Dá sùn : dá nìkan sùn = To sleep alone
-
Dá wà = To be alone
-
Oṣù ọ̀pẹ = December
-
Ojúkòkòrò = Coveteousness, Greed