-
Ìrántí = Remembrance, remember
-
Ipá = Force
-
Ọjọ́ ìbí = Birthday
-
Òótọ́ = Truth
-
Ọ̀dàlẹ̀ = Betrayer: betray
-
Ìdíbọ́n = Pretence, pretending, pretend
-
Àkóbá = Implicate, implicating
-
Ìfura = Suspect, suspicious, suspicion
-
Favorite = Ààyò
-
Irọ́ = liar, lie, lying
-
Òǹgbẹ = thirst
-
Ọwọ́ kún= busy
-
Ojúìse=Responsibility
-
Odì=Malice
-
Ojúṣàájú=bias
-
lawọ́= Generous: Open-handed
-
mu wa= To bring
-
Ìsojú= representation
-
Ìsèlú: Òsèlú= Politics
-
kọ́kọ́= First
-
ìpolówó--Advertisment
-
Irú wo= what type
-
Ìrírí= experience
-
Ìnkankínkàn:ounkóun=anything