-
Ìlàágùn = Sweat, sweating
-
Ìkẹ́kọ̀ọ́gboyè = Graduation, graduated
-
Òní = Today
-
Ààwẹ̀ = Fast or fasting
-
Jáde = to go out:going out:gone out:went out
-
Àná = Yesterday
-
Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò = Interview
-
Kúrò = leave, leaving, left
-
Ariwo = Noise
-
Ààbọ̀ = ìlàjì = ìdajì = Half
-
Oògùn = Medicine, charm
-
Ogun = War
-
Iparí ọ̀sẹ̀, òpin ọ̀sẹ̀ = Weekend, last weekend, next weekend
-
Iṣẹ́ ilé = House chores
-
Ìdáàbòbò = Protection, Security, Covering, Shield
-
Èrè = Profit, Gain
-
Oṣù tó kọjá = Last month
-
Ìjẹ́ta = Two days ago
-
Ọ̀sẹ̀ yí = This week.
-
Drum = Ìlù
-
Ìlú = town
-
Iṣé = Work, Profession, Occupation
-
Ìgbáradì = Preparation
-
Ọjọ́ ìṣẹ́gun = Tuesday