-
Mọ́jú = Overnight
-
Ọ̀rẹ́ = Friend
-
Ìwòyí = This time
-
Òfò = waste
-
Tijú = Shy
-
Ṣeéṣe = Possible
-
Kí = to greet
-
Ìbínú = anger
-
Sùúru = Patience
-
Kọ̀ = Refuse or reject
-
Àdììtú = Mystery
-
Àsíri = Secret
-
Ìyàlẹ́nu = Surprise, surprising
-
Ìyanu = Miracle
-
Aláàsírí = Confidant
-
Òjijì = Sudden,suddenly
-
Bìkítà=To care,concern,challant...
-
Ìkóríra = Hatred
-
Ìmọ tara ẹni nìkan= Self-Centeredness
-
The heated argument
-
Ìjákulẹ̀ = Disappointment
-
Ìkùnà = Failure
-
Òjìjí = Shadow
-
Ìrètí = Expectation, Expect