-
Ọkọ = Husband
-
Obìnrin = Woman
-
Ìyàwó = Wife
-
Àtẹnumọ́ = Importunate, insistence
-
Àlá = Dream
-
Ìpè = Call, beckon, invite
-
Ìtòsí = the line to : the lane to: nearby : close by : not far from
-
Iyàn jíjà = Argument, to argue
-
Ipá = Force
-
Ìtumọ̀ = Meaning
-
Àjọyọ̀ = Celebration
-
Àjọ̀dún = Anniversary
-
Ọ̀túnla = in two days time
-
Àrìnfẹsẹ̀sí = To be at the wrong place at the wrong time.
-
Ìjà = Fight
-
Ìkọ̀wéfiṣẹ́sílẹ̀ = Resignation, Resign
-
Bá rẹ́rìń = To laugh with someone
-
Ọ̀ṣẹ̀ tó ń bọ̀ = next week
-
Ọdún tó ń bọ̀ = Next year
-
Ìparí Oṣù = End of the month
-
Ọ̀sẹ̀ tó kọjá = Last week
-
Ìlù = drum
-
Ìlú = Town, city, community, state, country
-
Ìfitónilétí = Information