-
Fẹ́ràn = Like
-
Ìgbéraga = Pride
-
Osù Belu, Osù Kọkànlá = November
-
Ibẹ̀ = There
-
Ọjọ́ Ẹtì = Friday
-
Ọjọ́ bọ̀ = Thursday
-
Ètò = to plan, planning, arrangement...
-
Ọjọ́ àìkú = Sunday
-
Ibí = Here
-
Owú = Jealousy, jealous
-
Agídí = Obstinacy, stubbornness
-
Òye = Understanding, to understand
-
Ọjọ́ àbámẹ́ta = Saturday
-
Ìmọ̀ = Knowledge
-
Ojú ọjọ́ = Weather
-
Àforítì = Endurance
-
Àpèjúwe = Description
-
Àfojúdi = Belittle
-
Ìdàgbàsókè = Development, Growth
-
Àkótań = In conclusion, finally.
-
Ìtẹ̀síwájú = Progress, continuation, moving on...
-
Ìkà = wicked, wickedness, a wicked person
-
Ọkùnrin = Man
-
Ọmọdé = A child